Jeremaya 3:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ yipada, ẹ̀yin alaiṣootọ ọmọ,n óo mú aiṣootọ yín kúrò.“Wò wá! A wá sọ́dọ̀ rẹ,nítorí ìwọ ni OLUWA Ọlọrun wa.

Jeremaya 3

Jeremaya 3:15-25