Jeremaya 29:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé mo mọ èrò tí mò ń gbà si yín, èrò alaafia ni, kì í ṣe èrò ibi. N óo mú kí ọjọ́ ọ̀la dára fun yín, n óo sì fun yín ní ìrètí.

Jeremaya 29

Jeremaya 29:1-19