Jeremaya 29:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí aadọrin ọdún Babiloni bá pé, n óo mójú tó ọ̀rọ̀ yín, n óo mú ìlérí mi ṣẹ fun yín, n óo sì ko yín pada sí ibí yìí.

Jeremaya 29

Jeremaya 29:3-16