Jeremaya 26:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ahikamu ọmọ Ṣafani fọwọ́ sí ọ̀rọ̀ mi, kò sì jẹ́ kí á fà mí lé àwọn eniyan lọ́wọ́ láti pa.

Jeremaya 26

Jeremaya 26:19-24