Jeremaya 26:23 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n mú Uraya jáde ní ilẹ̀ Ijipti, wọ́n mú un tọ ọba Jehoiakimu wá. Ọba Jehoiakimu fi idà pa á, ó sì ju òkú rẹ̀ sí ibi tí wọn ń sin àwọn talaka sí.

Jeremaya 26

Jeremaya 26:22-24