Jeremaya 25:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́ igbe àwọn olùṣọ́-aguntanati ẹkún ẹ̀dùn ti àwọn oluwa agbo ẹran;nítorí OLUWA ń ba ibùjẹ ẹran wọn jẹ́.

Jeremaya 25

Jeremaya 25:28-38