Jeremaya 25:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní sí ààbò mọ́ fún àwọn olùṣọ́-aguntan, kò ní sí ọ̀nà ati sá àsálà fún àwọn oluwa àwọn agbo ẹran.

Jeremaya 25

Jeremaya 25:34-38