Jeremaya 25:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ariwo náà yóo kàn dé òpin ayé,nítorí pé OLUWA ní ẹjọ́ láti bá àwọn orílẹ̀-èdè rò.Yóo dá gbogbo eniyan lẹ́jọ́,yóo fi idà pa àwọn eniyan burúkú,OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.’ ”

Jeremaya 25

Jeremaya 25:21-32