Jeremaya 25:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun Israẹli sọ fún mi pé, “Gba ife ọtí ibinu yìí lọ́wọ́ mi, kí o fún gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí n óo rán ọ sí mu.

Jeremaya 25

Jeremaya 25:9-22