Jeremaya 25:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè ati àwọn ọba alágbára yóo sọ àwọn ará Babiloni pàápàá di ẹrú, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀san ìṣe wọn ati iṣẹ́ ọwọ́ wọn.”

Jeremaya 25

Jeremaya 25:10-17