Jeremaya 23:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú OLUWA kò ní rọ̀ títí yóo fi ṣe ohun tí ó pinnu lọ́kàn rẹ̀. Yóo ye wọn nígbà tí ọjọ́ ìkẹyìn bá dé.”

Jeremaya 23

Jeremaya 23:15-23