Jeremaya 23:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wo ibinu OLUWA bí ó ṣe ń jà bí ìjì! Ó ti fa ibinu yọ. Ó sì ń jà bí ìjì líle. Yóo tú dà sí orí àwọn eniyan burúkú.

Jeremaya 23

Jeremaya 23:9-29