Nítorí náà ọ̀nà wọn yóo dàbí ọ̀nà tí ń yọ̀ ninu òkùnkùn,a óo tì wọ́n sinu rẹ̀, wọn yóo sì ṣubú,nítorí n óo mú kí ibi bá wọn ní ọdún ìjìyà wọn.