Jeremaya 22:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ nípa ìdílé ọba Juda pé,“Bíi Gileadi ni o dára lójú mi,ati bí orí òkè Lẹbanoni.Ṣugbọn sibẹ, dájúdájú, n óo sọ ọ́ di aṣálẹ̀;o óo sì di ìlú tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé.

Jeremaya 22

Jeremaya 22:1-14