Jeremaya 22:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹ kò bá gba ohun tí mo wí, mo ti fi ara mi búra pé ilẹ̀ yìí yóo di ahoro. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Jeremaya 22

Jeremaya 22:1-6