Jeremaya 22:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA sọ nípa Jehoiakimu, ọba Juda, ọmọ Josaya pé,wọn kò ní dárò rẹ̀, pé,“Ó ṣe, arakunrin mi!”Tabi pé, “Ó ṣe, arabinrin mi!”Wọn kò ní ké pé,“Ó ṣe, oluwa mi!” Tabi pé, “Ó ṣe! Áà! Kabiyesi!”

Jeremaya 22

Jeremaya 22:12-27