Jeremaya 22:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn níbi èrè aiṣododo nìkan ni ojú ati ọkàn yín ń wà,níbi kí ẹ máa pa aláìṣẹ̀, kí ẹ máa ni eniyan lára,kí ẹ sì máa hùwà ìkà.

Jeremaya 22

Jeremaya 22:9-21