Jeremaya 2:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo ká ọwọ́ lérí ninígbà tí ẹ óo bá jáde níbẹ̀.Nítorí OLUWA ti kọ àwọn tí ẹ gbójúlé,wọn kò sì ní ṣe yín níre.”

Jeremaya 2

Jeremaya 2:27-37