Jeremaya 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

kí n lọ sí ìsàlẹ̀ àfonífojì ọmọ Hinomu, lẹ́nu Ibodè Àpáàdì; kí n sì kéde ọ̀rọ̀ tí òun óo sọ fún mi níbẹ̀:

Jeremaya 19

Jeremaya 19:1-3