Jeremaya 19:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní kí n lọ ra ìgò amọ̀ kan, kí n mú díẹ̀ ninu àwọn àgbààgbà ìlú ati àwọn bíi mélòó kan ninu àwọn àgbà alufaa,

Jeremaya 19

Jeremaya 19:1-8