Jeremaya 17:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àparò tíí pa ẹyin ẹlẹ́yinbẹ́ẹ̀ ni ẹni tí ó fi èrú kó ọrọ̀ jọ.Ọrọ̀ yóo lọ mọ́ ọn lọ́wọ́ lọ́sàn-án gangan,nígbẹ̀yìn yóo di òmùgọ̀.

Jeremaya 17

Jeremaya 17:1-19