Jeremaya 17:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi OLUWA ni èmi máa ń wádìí èrò eniyan,tí èmi sì máa ń yẹ ọkàn eniyan wò,láti san án fún olukuluku gẹ́gẹ́ bí ìṣe rẹ̀,ati gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Jeremaya 17

Jeremaya 17:5-11