Jeremaya 17:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Gègé irin ni a fi kọ ẹ̀ṣẹ̀ Juda sílẹ̀ gègé òkúta dayamọndi ni a sì fi kọ ọ́ sí ọkàn yín, ati sí ara ìwo ara pẹpẹ wọn,

Jeremaya 17

Jeremaya 17:1-8