Jeremaya 16:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Nítorí náà, wò ó, n óo jẹ́ kí wọn mọ̀;àní sẹ́, n óo jẹ́ kí wọ́n mọ agbára ati ipá mi;wọn yóo sì mọ̀ pé orúkọ mi ni OLUWA.”

Jeremaya 16

Jeremaya 16:16-21