Jeremaya 16:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ohun tí OLUWA sọ nípa àwọn ọmọkunrin ati àwọn ọmọbinrin tí a bí ní ibí yìí, ati nípa ìyá tí ó bí wọn, ati baba tí a bí wọn fún ni pé,

Jeremaya 16

Jeremaya 16:1-11