Jeremaya 12:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ ọ́ di ahoro,ilẹ̀ pàápàá ń ráhùn sí mi.Wọ́n ti sọ gbogbo ilẹ̀ náà di ahoro,ṣugbọn ẹnikẹ́ni kò bìkítà fún un.

Jeremaya 12

Jeremaya 12:9-17