Jeremaya 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ àwọn darandaran ni wọ́n ti ba ọgbà àjàrà mi jẹ́,wọ́n ti tẹ oko mi mọ́lẹ̀,wọ́n sọ oko mi dáradára di aṣálẹ̀.

Jeremaya 12

Jeremaya 12:2-17