Jeremaya 11:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní sí ẹni tí yóo ṣẹ́kù nítorí pé òun óo mú kí ibi dé bá àwọn ará Anatoti, nígbà tí àkókò bá tó tí òun óo jẹ wọ́n níyà.

Jeremaya 11

Jeremaya 11:22-23