Jeremaya 11:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun ní òun óo jẹ wọ́n níyà; àwọn ọdọmọkunrin wọn yóo kú lójú ogun, ìyàn ni yóo sì pa àwọn ọmọkunrin ati ọmọbinrin wọn.

Jeremaya 11

Jeremaya 11:16-23