Jẹnẹsisi 9:28-29 BIBELI MIMỌ (BM)

28. Ọọdunrun ọdún ó lé aadọta (350) ni Noa tún gbé sí i lẹ́yìn ìkún omi.

29. Noa kú nígbà tí ó di ẹni ẹgbẹrun ọdún ó dín aadọta (950).

Jẹnẹsisi 9