Jẹnẹsisi 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìran Noa nìyí: àwọn ọmọ rẹ̀ ni Ṣemu, Hamu ati Jafẹti. Lẹ́yìn ìkún omi, àwọn mẹtẹẹta bí ọmọ tiwọn.

Jẹnẹsisi 10

Jẹnẹsisi 10:1-9