Jẹnẹsisi 9:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹranko tí ó wà láyé, gbogbo ẹyẹ, gbogbo ẹja tí ń bẹ ninu omi, ati gbogbo ohun tí ń rìn káàkiri ni yóo máa bẹ̀rù yín, ìkáwọ́ yín ni mo fi gbogbo wọn sí.

Jẹnẹsisi 9

Jẹnẹsisi 9:1-5