Jẹnẹsisi 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun súre fún Noa ati àwọn ọmọ rẹ̀, ó ní, “Ẹ máa bímọ lémọ, kí ẹ máa pọ̀ sí i, kí ẹ sì kún gbogbo ayé.

Jẹnẹsisi 9

Jẹnẹsisi 9:1-10