Jẹnẹsisi 8:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Noa tẹ́ pẹpẹ kan fún OLUWA, ó mú ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn ẹran ati àwọn ẹyẹ tí wọ́n mọ́, ó fi wọ́n rúbọ lórí pẹpẹ náà.

Jẹnẹsisi 8

Jẹnẹsisi 8:18-22