Jẹnẹsisi 8:19 BIBELI MIMỌ (BM)

pẹlu gbogbo àwọn ẹranko, gbogbo àwọn ohun tí ń rìn káàkiri lórí ilẹ̀ ati àwọn ẹyẹ. Gbogbo àwọn ohun tí ń rìn káàkiri lórí ilẹ̀ patapata ni wọ́n bá Noa jáde kúrò ninu ọkọ̀.

Jẹnẹsisi 8

Jẹnẹsisi 8:12-22