Jẹnẹsisi 7:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu gbogbo ẹran tí ó bá jẹ́ mímọ́, mú wọn ní takọ-tabo, meje meje, ṣugbọn ninu gbogbo ẹran tí kò bá jẹ́ mímọ́, mú akọ kan ati abo kan.

Jẹnẹsisi 7

Jẹnẹsisi 7:1-12