Jẹnẹsisi 7:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá OLUWA sọ fún Noa pé, “Wọ inú ọkọ̀ lọ, ìwọ ati àwọn ará ilé rẹ, nítorí pé ìwọ nìkan ni o jẹ́ olódodo sí mi ní gbogbo ayé.

Jẹnẹsisi 7

Jẹnẹsisi 7:1-2