Jẹnẹsisi 7:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìkún omi wà lórí ilẹ̀ fún ogoji ọjọ́. Omi náà pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi léfòó lójú omi.

Jẹnẹsisi 7

Jẹnẹsisi 7:8-23