Jẹnẹsisi 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ohun ẹlẹ́mìí, akọ kan, abo kan, ní oríṣìí kọ̀ọ̀kan wọlé gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti pàṣẹ fún Noa. OLUWA bá ti ìlẹ̀kùn ọkọ̀ náà.

Jẹnẹsisi 7

Jẹnẹsisi 7:10-24