Jẹnẹsisi 6:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Kí o sì kó oniruuru oúnjẹ sinu ọkọ̀ náà fún ara rẹ ati fún wọn.”

22. Noa bá ṣe gbogbo ohun tí Ọlọrun pàṣẹ fún un.

Jẹnẹsisi 6