Jẹnẹsisi 50:8 BIBELI MIMỌ (BM)

ati gbogbo ìdílé Josẹfu àwọn arakunrin rẹ̀ ati ìdílé baba rẹ̀, àfi àwọn ọmọde, àwọn agbo ẹran, ati àwọn mààlúù nìkan ni ó kù sí ilẹ̀ Goṣeni.

Jẹnẹsisi 50

Jẹnẹsisi 50:1-13