Jẹnẹsisi 50:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu lọ sin òkú baba rẹ̀, gbogbo àwọn iranṣẹ Farao sì bá a lọ, ati gbogbo àwọn ẹmẹ̀wà ààfin ọba, ati gbogbo àwọn àgbààgbà ìlú Ijipti,

Jẹnẹsisi 50

Jẹnẹsisi 50:1-9