Jẹnẹsisi 50:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu rí ìran kẹta ninu àwọn ọmọ Efuraimu. Àwọn ọmọ tí Makiri ọmọ Manase bí, ọwọ́ Josẹfu ni ó bí wọn sí pẹlu.

Jẹnẹsisi 50

Jẹnẹsisi 50:18-26