Jẹnẹsisi 50:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu sì ń gbé ilẹ̀ Ijipti, òun ati ìdílé baba rẹ̀, ó gbé aadọfa (110) ọdún láyé.

Jẹnẹsisi 50

Jẹnẹsisi 50:20-26