Jẹnẹsisi 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí ó bí Seti, ó tún gbé ẹgbẹrin (800) ọdún láyé, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Jẹnẹsisi 5

Jẹnẹsisi 5:1-11