Jẹnẹsisi 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Adamu di ẹni aadoje (130) ọdún, ó bí ọmọkunrin kan. Ọmọ náà jọ ọ́ gidigidi, bí Adamu ti rí gan-an ni ọmọ náà rí. Ó bá sọ ọ́ ní Seti.

Jẹnẹsisi 5

Jẹnẹsisi 5:1-7