Jẹnẹsisi 48:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tèmi ni àwọn ọmọkunrin mejeeji tí o bí ní ilẹ̀ Ijipti kí n tó dé, bí Reubẹni ati Simeoni ti jẹ́ tèmi, bẹ́ẹ̀ náà ni Manase ati Efuraimu jẹ́ tèmi.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:1-10