Jẹnẹsisi 48:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, ‘N óo fún ọ ní ọpọlọpọ ọmọ, n óo sì sọ ọ́ di ọpọlọpọ ẹ̀yà, ati pé àwọn ọmọ ọmọ rẹ ni n óo fi ilẹ̀ náà fún, yóo sì jẹ́ tiwọn títí ayé.’

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:1-13