Jẹnẹsisi 48:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Israẹli sọ fún Josẹfu pé, “Àkókò ikú mi súnmọ́ etílé, ṣugbọn Ọlọrun yóo wà pẹlu rẹ, yóo sì mú ọ pada sí ilẹ̀ baba rẹ.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:13-22