Jẹnẹsisi 48:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá súre fún wọn ní ọjọ́ náà, ó ní,“Orúkọ yín ni Israẹli yóo fi máa súre fún eniyan,wọn yóo máa súre pé,‘Kí Ọlọrun kẹ́ ọ bí ó ti kẹ́ Efuraimu ati Manase.’ ”Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe fi Efuraimu ṣáájú Manase.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:17-22